ALL HAIL THE NEW ALAAFIN OBA AKEEM ABIMBOLA OWOADE, OWOADE 1
By Lanre Ogundipe Oríkì Sango! A bí lumo bí òwú Ọkọ̀ mi asọ̀ǹbọ̀-sọnbọ idà Ebiti káwọ́ sẹ́yìn soro bíi agbọ́n Ẹ̀bìtì ká ọwọ́ ìjà lérí Èyí tí yó ṣẹ ní àá ń wòye Sango! Sangiri làgiri Ò làgiri kàkà fìgbà ẹdùn bọ̀ A wọ̀lú tìlù tariwo Ṣàngó oooooo Ka-bi-ye-si Alase!… Continue reading













